Awon Okunfa Isubu Oro-aje Orile-ede
أعرض المحتوى باللغة العربية
Iyapa Olohun Allah ati owo ele ni okunfa meji ti o lagbara julo fun isubu oro-aje, imoran si tun waye lori awon ona abayo si isoro yii.