×
Image

Idajo Lilo Awon Aaya Al-kurani Fun Iwosan ( Rukya ) - (Èdè Yorùbá)

Fatwa yi je idahun si ibeere ti awon Musulumi maa n beere nipa lilo awon aaya Al-kurani lati fi se iwosan, yala ki eniyan ka a ni tabi ki o han si ori nkan ti o mo ki o si fo o, leyinnaa ki o mu u.

Image

Idajo wiwa iranlowo ni odo awon anabi Olohun ati awon ore Olohun - (Èdè Yorùbá)

Ibeere ti o waye ni aaye yi lo bayi pe: iko kan nso wipe: Ko leto ki a maa wa iranlowo ni odo awon anabi Olohun ati awon ore Olohun, iko miran nso wipe: o leto nitoripe ore Olohun ati aayo Re ni awon eniyan yi, ewo ninu iko mejeeji....

Image

Idajọ Nafila ni Ọjọ Alaruba ti o kẹhin ninu Osu Safar - (Èdè Yorùbá)

Idajo esin lori yiyan nafila ni ojo alaruba ti o kehin ninu osu Safar ati idajo esin lori wipe irufe nafila bee adadasile ninu esin ni.

Image

IDAJỌ GBIGBA AAWẸ OSU RAJAB - (Èdè Yorùbá)

Idajo gbigba aawe ninu osu Rajab bi apa kan ninu awon eniyan se maa n se pelu ero wipe osu naa da yato, awon onimimo si ti se alaye wipe adadaale ni gbogbo awon nkan wonyi.

Image

Idajo ki eniyan to ni iduro - (Èdè Yorùbá)

Fatwa yi so fun wa nipa bi o ti je wipe eniyan leto lati to ni iduro bi o tile je wipe ipile ni ki eniyan bere nigbati o ba fe to.

Image

Eni ti o n beru aisan, kinni yoo se? - (Èdè Yorùbá)

Eleyi ni idahun fun ibeere lori bi eniyan kan ba n beru aisan.

Image

Gbigba Aawe Ninu Gbogbo Awon Ojo Osu Rajab Ati Sha’baan - (Èdè Yorùbá)

Awon eniyan kan maa n gba aawe ninu gbogbo ojo osu Rajab at Sha’baan lehinnaa Ramadan, nje eri wa lori ohun ti won n se yi bi?